
Yoruba
Afrobeat popLyrics
*ÀBÁDÒFIN ỌMỌ ÌLÚ: ỌKỌ̀/IDÀ LÓRÍ ÌṢỌ̀KAN ỌMỌ YORÙBÁ*
Kéere ò!
Njẹ́ lẹ ẹ mọ̀ wípé àbádòfin HB Ẹgbẹ̀rún méjí lé ní mẹ́tàdínlọ́gọ́ta (2057) fẹ́ ẹ́ fi ọgbọ́n àlùmọ̀kọ́rọ́yín gba àṣà àti ìṣe wa dànù kúrò lọ́wọ́ wa nípa ṣíṣe ìjàmbá/àkóbá àti ìyẹpẹrẹ pẹ̀lú ìmùnnilẹ́rú fún àbáláíyé àti orírun ilẹ̀ wa.
A fẹ́ kí gbogbo wa mọ àmọ̀dájú wípé ìpìlẹ̀ wa kìí ṣe ti àfẹnujẹ́ lásán bí kìí ṣe nípa ti ẹ̀jẹ̀ ìbí, ìtàn tí kò ní àbàwọ́n, àṣà tó mú'ná d'óko àti orírun tí ò ní àbùkù. Kìí ṣe nípa gbígbé agbègbè tàbí ìlú kan fún ìgbà pípẹ́.
Jíjẹ́ ọmọ k'oótù oòjííre (Yorùbá) gbọdọ̀ jẹ́ nípa ìbí tàbí orírun, ìtàn, èdè, àṣà, ìrírí àti ẹ̀sìn - yálà pẹ̀lú àjùmọ̀sọ èdè tàbí ẹ̀sìn.
Yorùbá kó 'ni mọ́'ra. Ó sí fi ààyè gba t'onílé t'àlejò tí ó ṣe tán láti gbé ní gbogbo ilẹ̀kílẹ̀ tíí ṣe ti ọmọ k'oótù oòjííre. Ṣùgbọ́n èyí kò fi ààyè tàbí ànfààní sílẹ̀ láti ṣí àwọn ọmọ Yoòbá ní'dí kúrò níbi orírun wọn nípa lílo òfin orílẹ̀ èdè Nàìjíríyà.
Àwọn ìlú àti ìletò wa gbogbo pátápátá ló gbòòrò tí wọn sì jẹ́ onítẹ̀síwájú torí wípé a fi ààyè gba t'ẹrú t'ọmọ, a sì ní àfojúsún rere fún ọjọ́ ọ̀la ṣùgbọ́n èyí kò fi ààyè sílẹ̀ fún ìyannijẹ tàbí ìṣíwanídìí kúrò ní orírun wa.
Orílẹ̀ èdè Nàìjíríyà nílò àti ṣe àtúntò ilẹ̀ Nàìjíríyà ní ìlànà ẹ̀yà àti ẹ̀sín láti f'ààyè gba kóówá kí olúkúlùkù lè má a ṣe ìjọba lórí ara wọn pẹ̀lú ohun tí wọ́n bá yàn láàyò lórí àdámọ́ wọn àti àfojúsùn wọn gẹ́gẹ́ bíi orílẹ̀ èdè parapọ̀.
Àwọn èèyàn orílẹ̀ èdè Nàìjíríyà yíò má a rìn má a yan pẹ̀lú ìbáṣepọ̀/àjọṣepọ̀ tó dán mọ́rán ṣùgbọ́n ààlà á f'ojú họ̀n làti dẹ́kun aáwọ̀/ìjà. Èyí ni yíò ṣe atọ́kùn ìtẹ̀ṣíwájú, àṣeyọrí àti ìgbéga fún orílẹ̀ èdè wa Nàìjíríyà.
_*CHORUS (Song)*_
Nípa ìmúnnisìn, a gbọdọ̀ ké gbàjarè. Àwa ọmọ k'oótù oòjííre, a ò níí bẹ̀rù/fòyà. A má a jà fún ẹ̀tọ́ wa láìbìkítà.
A ṢỌ WÍPÉ KÒ SÍ ÀÀYÈ FÚN ÀBÁDÒFIN ỌMỌ ÌLÚ!
ÀWA ỌMỌ K'OÓTÙ OÒJÍÍRE WÍPÉ KÒ SÍ ÀÀYÈ FÚN ÀBÁDÒFIN ỌMỌ ÌLÚ!
Создайте свою ИИ-песню за секунды с Voices AI
Голосовые озвучки знаменитостей и киногероев, ИИ-музыка, клонирование голоса, улучшение аудио и многое другоеСкачатьОткройте для себя будущее музыки с нашей библиотекой ИИ-сгенерированных песен
Добро пожаловать в следующее поколение создания музыки с нашей библиотекой ИИ-песен, где инновационный искусственный интеллект встречается с творческим самовыражением. Исследуйте обширную коллекцию пользовательских ИИ-песен различных жанров, настроений и языков.
Независимо от того, являетесь ли вы создателем контента, разработчиком игр, подкастером или просто любителем музыки, наша библиотека ИИ-песен предлагает что-то для каждого.
Ключевые особенности нашей библиотеки ИИ-песен:
- Широкий выбор жанров: Откройте для себя песни различных жанров, таких как поп, рок, хип-хоп, классика, джаз, эмбиент и другие, все сгенерированные передовой ИИ-технологией.
- Настройка настроения и тона: Легко находите или создавайте треки, которые соответствуют вашему настроению - будь то энергичные, спокойные, драматические или вдохновляющие, наши ИИ-песни предлагают идеальную атмосферу.
- Многоязычные тексты: Наша библиотека включает песни на нескольких языках, включая английский, немецкий, испанский и многие другие.
- Идеально для мультимедиа: Используйте наши ИИ-песни для фоновой музыки, звуковых эффектов или как уникальное дополнение к вашим видео, подкастам и презентациям.
Почему выбирают наши ИИ-сгенерированные песни?
- Высокое качество звука: Наши ИИ-песни разработаны, чтобы звучать естественно и профессионально.
- Бесконечная креативность: Благодаря ИИ-настройке, каждая песня может быть уникально адаптирована под ваши потребности.
- Глобальная доступность: Наша многоязычная поддержка означает, что ваша музыка может привлекать слушателей со всего мира.
- Простая интеграция: Загружайте и интегрируйте песни легко в существующие рабочие процессы.
Просмотрите нашу библиотеку ИИ-песен прямо сейчас, чтобы исследовать музыку, созданную пользователями с помощью передовых ИИ-технологий.